Información de la canción En esta página puedes encontrar la letra de la canción Iba, artista - Aṣa. canción del álbum Beautiful Imperfection, en el genero Иностранная авторская песня
Fecha de emisión: 04.09.2011
Etiqueta de registro: Naïve Records
Idioma de la canción: español
Iba |
Oru sẹ ileku, |
I wanna have some talk, with you-o |
Nitori rẹ mo sẹ lola |
Nitori rẹ mo sẹ sogẹ |
Nitori rẹ mo sẹ ra moto |
Mo wo lẹ, mo boluwa mi soro |
Nitori rẹ mo sẹ wa laiye |
Nitori rẹ mo sẹ wa so sara |
Nitori re moji lowuro |
Mo wo aye mi lo de ye ya |
Aa aho ha ha a ha |
Iba fi ele |
iba fi eledua |
Aa ho ho a ho |
Mo mo le ye |
mo boluwa mi soro |
Nitori re mo sẹ gbo |
Iroyin ayo |
lai so owo |
lai si nkan kan |
I ya oni layo la o o |
boluwa se wi be na lori |
Oh oh o wi kpe kim ma se beru |
So aho ho a ho a a ho |
Aa aho ha ha a ha |
Iba fi ele |
iba fun eledua |
mo wo le |
mo boluwa mi soro |
Ninu ikpon ju |
Ninu i damu |
be emi ba gbo ro |
ma wo lẹ ma boluwa mi soro |
bẹ emi o lẹ yọ |
ba aye ba fi oju dẹ mi |
be emi oni ile |
ma wo le ma boluwa mi soro |
Aa aho ha ha a ha |
iba fi ele |
iba fun eledua |
iba o o o o |
mo wo le ye |
mo boluwa mi soro |
O o o mi |
Ninu ikpon ju |
Ninu idamu |
be mi ba gbo ro |
ma wo le ma boluwa mi soro |
mo o ni foju sunku mo o o o |
aye lo ja, orun ni ile |
ẹni a fi ba mi |
iba O O O |